Ọ̀rọ̀ Pàtàkì

Mo ti yan ọ̀rọ̀ àti gbólóhùn tí mo nífẹ̀ẹ́ pupọ̀ láti iṣẹ́ mi àti òwe náà





Àwọn àgbàlagbà wí pé: 

Báa gún iyán nínú ewé, táa se ọbẹ̀ nínú èpo ẹpà, ẹni máa yó, á yó.

Ẹ̀wẹn gbọ́:

Àwa gbúdọ̀ tọ́jú ìfẹ́ ẹni, àyànfẹ́ ẹni, òun ọ̀nìyọ̀n yíyùn ẹni. Ká a éè lè ṣe, àwa máa gbé náyé ìfẹ́ ẹni rìí àwa ti bàjẹ́ pẹ̀lú ọwọ́ ẹni.

Ẹ̀wẹn kà:

Ẹ̀wẹ̀n jẹ́ ìmọ́lẹ̀ kó bá tàn yòò rí yàrá ọ̀nìyàn. Núgbà kẹ́wẹ̀n bá wà rúlé wẹ̀n, tàbí rọ́jà, ubokúbo wẹ̀n wà, ìmọ́lẹ̀ ré wẹ̀n máa jẹ́ náyé rí dede ẹni.