Ijewo igbagbo je asayan awon oro agbara ti a fa yo lati inu Oro Olorun.
Bibeli wipe, “Ọ̀rọ ẹnu enia ni yio mu inu rẹ̀ tutu: ibisi ẹnu rẹ̀ li a o si fi tù u ninu. Ikú ati ìye mbẹ ni ipa ahọn: awọn ẹniti o ba si nlò o yio jẹ ère rẹ̀.” (Iwe Owe 18:28-21)
Fi oro Olorun si ahon re nipa awon ijewo yii loorekoore, ayipada nla yoo si ba aye re loruko Jesu. Amin.