E darapo mo wa lori Telegram
Oun ti o ye ki eniyan gbo lati di eni igbala. Eko yii tan imole si bi a se le waasu fun awon ti nsegbe lo. Download
Leyin ti mo ti di eni igbala, ki lo ye ki n mo? Download
Kini pataki ifedefo? Awon wo gan gan ni ifedefo wa fun?
Download
Alaye lekunrere nipa oun ti Jesu Oluwa se nipa iku ati ajinde Re.
Iha wo ni Olorun ko si ese? Kini Jesu Oluwa se pelu eje Re?
Oun ti o ye ki Onigbagbo mo nipa Emi mimo
Alaye oun to sele ninu Iwe Ise Awon Aposteli ori keji
Ẹni tí Ọlọ́run bá ti sọ di mímọ́ nìkan lo leè gbé ìgbé ayé ìwà-mímọ́ to tẹ́ Ọlọ́run lọ́run.