head -orí
eye – ojú
ear – etí
mouth – ẹnu
tongue – ahọ́n
lip - ètè
teeth – eyín
chin – àgbọ̀n
arm - apá
hand - ọwọ́
back - ẹ̀yìn
leg - ẹsẹ̀
BRAINWORK
1 One head – ------------------------------------------------
2 --------------------------- – Ojú méjì
3 The third finger – ìka-ọwọ́ – -----------
4 Teeth – ---------------
5 Stomach – ----------------------------
6 ----------------------------- – ẹ̀hìn
7 Forehead – ----------------------------
8 ---------------------- – ẹnu
9 The second ear – -----------------
10 One leg – -----------------
11 ----------------- – ìka-ẹsẹ̀ mẹ́wàá
1. My head aches/I have headache – Orí n fọ mi.
2. My ear aches – Etí n ro mi
3. Raymond had toothache – Eyín n ro Raymond.
hair – irun
forehead – iwájú-orí
nose – imú
neck – ọrùn
soulder – èjìká
chest – àyà
stomach – ikùn
wrist – ọrùn-ọwọ́
finger – ìka-ọwọ́
thigh – itan
knee – orúnkún
buttock - ìbàdí
shin – ojùgun
toe – ìka-ẹsẹ̀