YORUBA TERMS ON BUILDING/HOUSEHOLD ITEMS

;
 
BUILDING
 

Ceiling – àjà

Roof – òrùlé

Roofing sheet – páànú

Roofing – ríró ilé

Wall – ògiri

Fence – odi

Window – fèrèsè

Door – ilẹkun

Carved door – aasẹ

Pillar – òpó

Beams – arópòódògiri

Corner – igununlé

Backyard – ẹhìnkùùlé

Frontage – iwájùúlé

Entrance – ojúulé; ẹnu ọna

Corridor – ọdẹdẹ

Courtyard – igbẹjọ

Veranda – ojúde

 Lobby – abawọle

Dining – ibi -ijẹun

Kitchen – ilé ìdáná

Hearth – ààrò

Toilet – ilé igbọnsẹ

Bathroom – ilé iwẹ

Gate – ìloro

Plastering – irẹle, rirẹ ilé

Well – kànga

Lamp – àtùpà

Ladder – àkàbà; akasọ

KITCHEN UTENSILS

 

 

 1. teaspoon - şíbí tọbele
 2. tablespoon – şíbí ìjẹun
 3. fork – şíbí oníga
 4. serving spoon – şíbí ìbù-njẹ
 5. breakable plates – àwo
 6. unbreakable plates - abọ; abọ́máfọ̀ọ́
 7. serving dish – àwo ìjẹun
 8. tray - ọpọn
 9. frying pan – agbada idinran
 10. stove – sitoofu
 11. water pot – ìkòkò omi
 12. cooking pot –  ìkòkò  ìdáná
 13. stool – àpótí
 14. wooden spoon – şíbí onípọn
 15. cup – ife
 16. cutting saucer - igbakọ
 17. stirring stick - orógù̀n
 18. Pillow - ìrọ̀rí
 19. Knife - ọ̀bẹ
 20. bed  - ibùsùn
 21.  hearth - ààrò
 22. cooking tripod - àdògán